Acts 3:5 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ọkunrin náà bá ń wò wọ́n, ó ń retí pé wọn yóo fún òun ní nǹkan.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O si fiyesi wọn, o nreti ati ri nkan gbà lọwọ wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó sì fiyèsí wọn, ó ń réti láti rí nǹkan gbà lọ́wọ́ wọn.