Acts 7:1 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Olórí Alufaa bá bi í pé, “Ṣé bẹ́ẹ̀ ni ọ̀ràn náà rí?”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
NIGBANA li olori alufa wipe, Nkan wọnyi ha ri bẹ̃ bi?
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà ni olorí àlùfáà wí pé, “Òtítọ́ ha ni àwọn ẹ̀sùn tí wọ́ fi kàn ọ́ bí?”