Acts 7:15 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Jakọbu bá lọ sí Ijipti. Níbẹ̀ ni ó kú sí, òun ati àwọn baba wa náà.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Jakọbu si sọkalẹ lọ si Egipti, o si kú, on ati awọn baba wa,
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà ni Jákọ́bù sọ̀kalẹ̀ lọ sí Íjíbítì, ní ibi tí òun àti àwọn baba wa kú sí.