Acts 7:43 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ṣebí àtíbàbà Moleki ni ẹ gbé rù, ati ìràwọ̀ Refani oriṣa yín, àwọn ère tí ẹ ṣe láti máa foríbalẹ̀ fún? N óo le yín lọ sí ìgbèkùn, ẹ óo kọjá Babiloni.’
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ẹnyin si tẹwọgbà agọ́ Moloku, ati irawọ oriṣa Remfani, aworan ti ẹnyin ṣe lati mã bọ wọn: emi ó si kó nyin lọ rekọja Babiloni.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ẹ̀yin sì tẹ́wọ́gba ojúbọ Mólókù, àti ìràwọ̀ Ráfánì òrìṣà yín, àwọn òrìṣà tí ẹ̀yin ṣe láti máa bọ. Nítorí náà èmi yóò kó yín lọ sí ìgbèkùn rékọjá Bábílónì.’

Recommended Reading