Amos 1:10 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nítorí náà n óo sọ iná sí orí odi ìlú Tire, yóo sì jó ibi ààbò rẹ̀ ní àjórun.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn emi o rán iná kan sara odi Tire, ti yio jo ãfin rẹ̀ wọnni run.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Èmi yóò rán iná sí ara odi Tírè Tí yóò jó gbogbo àwọn ààfin rẹ̀ run.”