Amos 1:12 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nítorí náà, n óo rán iná sí ìlú Temani, yóo sì jó ibi ààbò Bosira ní àjórun.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn emi o rán iná kan si Temani, ti yio jó afin Bosra wọnni run.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Èmi yóò rán iná sí orí Témánì Tí yóò jó gbogbo ààfin Bósírà run.”