Amos 1:14 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nítorí náà, n óo sọ iná sí orí odi ìlú Raba, yóo sì jó ibi ààbò rẹ̀ ní àjórun. Ariwo yóo sọ ní ọjọ́ ogun, omi òkun yóo ru sókè ní ọjọ́ ìjì;
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn emi o da iná kan ninu odi Rabba, yio si jó ãfin rẹ̀ wọnni run, pẹlu iho ayọ̀ li ọjọ ogun, pẹlu ijì li ọjọ ãjà:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Èmi yóò rán iná sí ara odi Rábà Èyí tí yóò jó àwọn ààfin rẹ̀ run pẹ̀lú igbe ní ọjọ́ ogun pẹ̀lú ìjì ní ọjọ́ ààjà