Amos 1:15 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
ọba wọn ati àwọn ìjòyè rẹ̀ yóo sì lọ sí ìgbèkùn.” OLUWA ló sọ bẹ́ẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ọba wọn o si lọ si igbèkun, on ati awọn ọmọ-alade rẹ̀ pọ̀, li Oluwa wi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ọba wọn yóò sì lọ sí ìgbèkùn Òun àti àwọn ọmọ aládé rẹ̀ lápapọ̀,” ni OLÚWA wí.