Amos 1:4 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nítorí náà, n óo sọ iná sí ààfin Hasaeli, yóo sì jó ibi ààbò Benhadadi kanlẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn emi o rán iná kan si ile Hasaeli, ti yio jo ãfin Benhadadi wọnni run.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Èmi yóò rán iná sí ilé Hásáélì Èyí ti yóò jó àwọn ààfin Bẹni-Hádádì run.