Amos 2:10 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Èmi fúnra mi ni mo mu yín jáde wá láti ilẹ̀ Ijipti, mo mu yín la aṣálẹ̀ fún ogoji ọdún, kí ẹ lè gba ilẹ̀ àwọn ará Amori.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Emi mu nyin goke pẹlu lati ilẹ Egipti wá, mo si sìn nyin li ogoji ọdun là aginjù ja, lati ni ilẹ awọn Amori.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Èmi mú un yín gòkè láti ilẹ̀ Éjíbítì wá, mo sì sìn yín la ihà já ní ogójì ọdún láti fi ilẹ̀ àwọn ará Ámórì fún un yín.