Amos 2:16 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ìhòòhò ni àwọn akọni láàrin àwọn ọmọ ogun yóo sálọ ní ọjọ́ náà.” OLUWA ló sọ bẹ́ẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati ẹniti o gboiyà ninu awọn alagbara yio salọ ni ihòho li ọjọ na, li Oluwa wi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
àní jagunjagun tí ó gbóyà jùlọ yóò sálọ ní ìhòòhò ní ọjọ́ náà,” ni OLÚWA wí.