Amos 2:3 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
n óo sì pa ọba ati àwọn ìjòyè rẹ̀ run.” OLUWA ló sọ bẹ́ẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Emi o si ké onidajọ kurò lãrin rẹ̀, emi o si pa gbogbo ọmọ-alade inu rẹ̀ pẹlu rẹ̀; li Oluwa wi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Èmi yóò ké onídájọ́ rẹ̀ kúrò Èmi yóò sì pa gbogbo àwọn ọmọ aládé rẹ́ nínú rẹ̀,” ni OLÚWA wí;