Amos 2:5 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nítorí náà, n óo sọ iná sí Juda, yóo sì jó àwọn ibi ààbò Jerusalẹmu ní àjórun.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn emi o rán iná kan sara Juda, yio si jó ãfin Jerusalemu wọnni run.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Èmi yóò rán iná sí orí Júdà Èyí tí yóò jó àwọn ààfin Jérúsálẹ́mù run.”