Amos 3:10 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
“Àwọn eniyan wọnyi ń kó nǹkan tí wọ́n fi ipá ati ìdigunjalè gbà sí ibi ààbò wọn, wọn kò mọ̀ bí à á tíí ṣe rere.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori nwọn kò mọ̀ bi ati ṣe otitọ, li Oluwa wi, nwọn ti kó ìwa-ipá ati ìwa-olè jọ li ãfin wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Wọn kò mọ bí wọ́n ṣe ń ṣe rere,” ni OLÚWA wí, “Ẹni tí ó gba àwọn ìwà ipá àti olè sí ààfin rẹ̀.”