Amos 4:5 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ẹ fi burẹdi tí ó ní ìwúkàrà rú ẹbọ ọpẹ́, ẹ kéde ẹbọ àtinúwá, kí ẹ sì fọ́nnu nípa rẹ̀; nítorí bẹ́ẹ̀ ni ẹ fẹ́ máa ṣe, ẹ̀yin ọmọ Israẹli.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ki ẹ si ru ẹbọ ọpẹ́ pẹlu iwukara, ẹ kede, ki ẹ si fi ọrẹ atinuwa lọ̀: nitori bẹ̃li ẹnyin fẹ́, ẹnyin ọmọ Israeli, li Oluwa Ọlọrun wi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Kí ẹ mú ọrẹ́ ìdúpẹ́ ìyẹ̀fun tí a sun kí ẹ sì mú ọrẹ àtinúwá lọ fi wọ́n yagàn, ẹ̀yin ènìyàn Ísírẹ́lì, nítorí èyí ni ẹ fẹ́ láti ṣe,” ni OLÚWA Ọlọ́run wí.