Amos 5:13 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nítorí náà, ẹni tí ó bá gbọ́n yóo dákẹ́ jẹ́ẹ́ ní irú àkókò yìí, nítorí pé àkókò burúkú ni.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitorina ẹni-oye yio dakẹ nigbana; nitori akòko ibi ni.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ọlọgbọ́n máa ń dákẹ́ jẹ́ẹ́ ní àkókò wọ̀nyí Nítorí búburú ni gbogbo ọjọ́.