Amos 5:14 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ire ni kí ẹ máa wá, kì í ṣe ibi kí ẹ lè wà láàyè; nígbà náà ni OLUWA Ọlọrun àwọn ọmọ ogun yóo wà pẹlu yín, bí ẹ ti jẹ́wọ́ rẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ẹ ma wá ire, kì isi iṣe ibi, ki ẹ ba le yè; bẹ̃ni Oluwa, Ọlọrun awọn ọmọ-ogun, yio si pẹlu nyin, bi ẹnyin ti wi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wá rere, má ṣe wá búburú kí ìwọ ba à le yè Nígbà náà ni OLÚWA alágbára yóò wà pẹ̀lú ù rẹ. Òun yóò sì wà pẹ̀lú ù rẹ bí ìwọ ṣe wí