Amos 5:17 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Wọn yóo sọkún ninu gbogbo ọgbà àjàrà yín, nítorí pé n óo gba ààrin yín kọjá. Èmi OLUWA ni mo sọ bẹ́ẹ̀.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati ni gbogbo ọ̀gba àjara ni isọkún yio gbe wà: nitori emi o kọja lãrin rẹ, li Oluwa wi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ìpohùnréré ẹkún yóò wà ní gbogbo ọgbà àjàrà Nítorí èmi yóò la àárin yín kọjá,” ni OLÚWA wí.