Amos 5:27 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nítorí náà, n óo ko yín lọ sí ìgbèkùn níwájú Damasku.” OLUWA, tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Ọlọrun àwọn Ọmọ Ogun, ni ó sọ bẹ́ẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitorina, emi o mu ki ẹ lọ si igbèkun rekọja Damasku, li Oluwa wi, Ọlọrun awọn ọmọ-ogun li orukọ rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí náà èmi yóò rán an yín lọ sí ìgbèkùn ní ìkọjá Dámásíkù,” ni OLÚWA wí, ẹni tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Ọlọ́run alágbára.