Amos 5:9 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Òun ni ó ń mú ìparun wá sórí àwọn alágbára, kí ìparun lè bá ibi ààbò wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ti o mu iparun kọ manà sori alagbara, tobẹ̃ ti iparun yio wá si odi agbara.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó fọ́n ìparun sí ìlú olódi Tí ó sì sọ àwọn ibùgbé àwọn ọmọ aládé di ahoro