Amos 6:1 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ègbé ni fún àwọn tí wọ́n wà ninu ìdẹ̀ra ní Sioni, ati àwọn tí wọn ń gbé orí òkè Samaria láìléwu, àwọn eniyan ńláńlá ní Israẹli, tí ó jẹ́ àkọ́kọ́ láàrin àwọn orílẹ̀-èdè, àwọn tí àwọn eniyan gbójúlé.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
EGBE ni fun ẹniti ara rọ̀ ni Sioni, ati awọn ti o gbẹkẹ̀le oke nla Samaria, awọn ti a pè ni ikini ninu awọn orilẹ-ède, awọn ti ile Israeli tọ̀ wá!
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ègbé ni fún ẹ̀yin tí ará rọ̀ ní Síónì àti ẹ̀yin tí ẹ wà ní abẹ́ ààbò ní òkè Samaríà àti ẹ̀yin olókìkí orílẹ̀-èdè tí ẹ̀yin ènìyàn Ísírẹ́lì máa ń tọ̀ ọ́ wá