Amos 6:11 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Wò ó! OLUWA pàṣẹ pé, a óo wó àwọn ilé ńlá, ati àwọn ilé kéékèèké lulẹ̀ patapata.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori kiyesi i, Oluwa paṣẹ, yio si fi iparun kọlù ile nla na, ati aisàn kọlù ile kékèké.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí OLÚWA tí pa àṣẹ náà, Oun yóò sì wó ilé ńlá náà lulẹ̀ túútúú Àti sísán kọlu ilé kékèké.