Amos 6:9 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Bí ó bá ku eniyan mẹ́wàá ninu ìdílé kan, gbogbo wọn yóo kú.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Yio si ṣe, bi enia mẹwa li o ba kù ninu ile kan, nwọn o si kú.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Bí Ọkùnrin mẹ́wàá bá sẹkù nínú ile kan, àwọn náà yóò kú