Amos 7:16 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Gbọ́ ọ̀rọ̀ OLUWA nisinsinyii, ṣé o ní kí n má sọ àsọtẹ́lẹ̀ fún àwọn ọmọ Israẹli mọ́, kí n má sì waasu fún àwọn ọmọ Isaaki mọ́?
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Njẹ nisisiyi, iwọ gbọ́ ọ̀rọ Oluwa: Iwọ wipe, Máṣe sọtẹlẹ̀ si Israeli, má si jẹ ki ọ̀rọ rẹ kán silẹ si ile Isaaki.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí náà nísinsin yìí, gbọ ọ̀rọ̀ OLÚWA. Ìwọ wí pé, “ ‘Má ṣe sọ àṣọtẹ́lẹ̀ sí Ísírẹ́lì Má ṣì ṣe wàásù sí ilé Ísáákì.’