Amos 8:12 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Wọn yóo máa lọ káàkiri láti òkun dé òkun, láti ìhà àríwá sí ìhà ìlà oòrùn. Wọn yóo máa sá sókè sódò láti wá ọ̀rọ̀ Ọlọrun, ṣugbọn wọn kò ní rí i.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nwọn o si ma rìn kiri lati okun de okun, ati lati ariwa ani titi de ila-õrun, nwọn o sare siwá sẹhìn lati wá ọ̀rọ Oluwa, nwọn kì yio si ri i.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ènìyàn yóò rìn kiri láti òkun dé òkun wọn yóò sì máa rìn ká láti gúṣù sí àríwá, wọn yóò máa wá ọ̀rọ̀ OLÚWA ṣùgbọ́n wọn kì yóò rí i.