Amos 8:13 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nígbà tó bá yá, àwọn ọdọmọkunrin ati àwọn wundia yóo dákú nítorí òùngbẹ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Li ọjọ na li awọn arẹwà wundia, ati awọn ọdọmọkunrin yio daku fun ongbẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Ní ọjọ́ náà “àwọn arẹwà wúndíá àti àwọn alágbára ọ̀dọ́mọkùnrin yóò dákú fún òùngbẹ omi.