Amos 8:14 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Gbogbo àwọn tí wọn ń fi oriṣa Aṣima ti Samaria búra, tí wọn ń wí pé: ‘Bí oriṣa rẹ ti wà láàyè, ìwọ Dani,’ ati, ‘Bí ọ̀nà Beeriṣeba ti wà láàyè;’ gbogbo wọn yóo ṣubú, wọn kò sì ní dìde mọ́.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ti o fi ẹ̀ṣẹ Samaria bura, ti nwọn si wipe, Iwọ Dani, ọlọrun rẹ mbẹ lãyè! ati ọ̀na Beerṣeba mbẹ lãyè! ani nwọn o ṣubu, nwọn kì yio si tún dide mọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn tí ó fi òrìṣà Samaríà búra tí wọ́n wí pé, ‘tí wọ́n sì wí pé, ìwọ Dánì, ọlọ́run rẹ ń bẹ láàyè,’ àti bi ó ti dájú pé ọlọ́run Báṣébà ti ń bẹ láàyè àní, wọn yóò ṣubú, wọn kì yóò sì tún dìde mọ́.’ láàyè ìwọ Dánì.’ Bí ó ti dájú pè ọlọrun rẹ ń bẹ láàyè ìwọ Báṣébà Wọ́n yóò ṣubú, Wọn kì yóò si tún díde mọ.”