Amos 9:10 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Gbogbo àwọn tí wọn ń dẹ́ṣẹ̀ láàrin àwọn eniyan mi ni ogun yóo pa, gbogbo àwọn tí wọ́n ń sọ pé, ‘Ibi kankan kò ní bá wa!’
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Gbogbo awọn ẹlẹṣẹ ninu enia mi yio ti ipa idà kú, ti nwipe, Ibi na kì yio le wa ba, bẹ̃ni kì yio ba wa lojijì.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Gbogbo àwọn ẹlẹ́sẹ̀ láàrin àwọn ènìyàn mi ni yóò ti ipa idà kú gbogbo àwọn ti ń wí pé Aburú kì yóò lé wa bá, bẹ́ẹ̀ ni kì yóò ká wa mọ́? A mú Ísírẹ́lì padà bọ̀ sípò.