Amos 9:15 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
N óo fẹsẹ̀ àwọn eniyan mi múlẹ̀ lórí ilẹ̀ tí mo fún wọn, a kò sì ní ṣí wọn nípò pada mọ́ lórí ilẹ̀ tí mo fún wọn. Èmi OLUWA Ọlọrun yín ni mo sọ bẹ́ẹ̀.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Emi o si gbìn wọn si ori ilẹ wọn, a kì yio si fà wọn tu mọ kuro ninu ilẹ wọn, ti mo ti fi fun wọn, li Oluwa Ọlọrun rẹ wi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Èmi yóò gbin Ísírẹ́lì sí orí ilẹ̀ rẹ̀. A kì yóò sì fà wọn tu mọ́ láéláé kúrò ni orí ilẹ̀ ti mo fi fún wọn,” ni OLÚWA Ọlọ́run rẹ wí.