Colossians 3:6 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nítorí nǹkan wọnyi ni ibinu Ọlọrun ṣe ń bọ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori ohun tí ibinu Ọlọrun fi mbọ̀wa sori awọn ọmọ alaigbọran.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Lórí àwọn wọ̀nyìí ni ìbínú Ọlọ́run ńbọ̀ wá.