Daniel 1:6 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Daniẹli, ati Hananaya, ati Miṣaeli ati Asaraya wà lára àwọn tí wọ́n ṣà ninu ẹ̀yà Juda.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Njẹ ninu awọn wọnyi ni Danieli, Hananiah, Miṣaeli, ati Asariah, lati inu awọn ọmọ Juda:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Lára àwọn wọ̀nyí ni àwọn tó wá láti Júdà: Dáníẹ́lì, Hananíáyà, Mísáẹ́lì àti Ásáríyà.