Daniel 1:9 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ọlọrun jẹ́ kí Daniẹli bá ojurere ati àánú olórí àwọn ìwẹ̀fà náà pàdé.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ọlọrun sa ti mu Danieli ba ojurere ati iyọ́nu pade lọdọ olori awọn iwẹfa.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ọlọ́run mú kí Dáníẹ́lì rí ojúrere àti àánú gbà láti ọwọ́ olórí àwọn ìwẹ̀fà,