Daniel 12:8 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Mo gbọ́ tí ó ń sọ̀rọ̀, ṣugbọn ohun tí ń sọ kò yé mi. Mo bá bèèrè pé, “Olúwa mi, níbo ni nǹkan wọnyi yóo yọrí sí?”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Emi si gbọ́, ṣugbọn kò ye mi: nigbana ni mo wipe, Oluwa mi, kini yio ṣe ikẹhin wọnyi?
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Èmi gbọ́, ṣùgbọ́n kò yé mi. Nígbà náà ni mo bèèrè pé, “OLÚWA mi, kí ni yóò jẹ́ àbábọ̀ àwọn nǹkan wọ̀nyí?”