Daniel 2:36 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
“Àlá náà nìyí; nisinsinyii, n óo sọ ìtumọ̀ rẹ̀ fún ọba.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Eyiyi li alá na; awa o si sọ itumọ rẹ̀ pẹlu niwaju ọba.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Èyí ni àlá náà, nígbà yìí ni a ó wá sọ ìtumọ̀ rẹ̀ fún ọba.