Daniel 3:30 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ọba bá gbé Ṣadiraki, Meṣaki ati Abedinego sí ipò gíga ní ìgbèríko Babiloni.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbana ni ọba gbé Ṣadraki, Meṣaki, ati Abednego leke ni igberiko Babeli.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà ni ọba gbé Ṣádírákì, Méṣákì àti Àbẹ́dinígò ga ní gbogbo agbégbé ìjọba Bábílónì.