Daniel 5:26 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ìtumọ̀ rẹ̀ sì nìyí: MENE, Ọlọrun ti ṣírò àwọn ọjọ́ ìjọba rẹ, ó sì ti parí rẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Eyi ni itumọ ohun na: MENE, Ọlọrun ti ṣirò ijọba rẹ, o si pari rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Èyí ni nǹkan tí ọ̀rọ̀ náà túmọ̀ sí: Mene: Ọlọ́run ti sírò ọjọ́ ìjọba rẹ. Ó sì ti mú u wá sí òpin.