Daniel 5:30 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ní alẹ́ ọjọ́ náà gan-an ni wọ́n pa Beṣasari, ọba àwọn ará Kalidea.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Loru ijọ kanna li a pa Belṣassari, ọba awọn ara Kaldea.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ní alẹ́ ọjọ́ náà ni a pa Beliṣáṣárì, ọba Bábílónì.