Daniel 7:10 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Iná ń ṣàn jáde bí odò níwájú rẹ̀. Ẹgbẹẹgbẹrun ọ̀nà ẹgbẹẹgbẹrun ni àwọn tí ń ṣe iranṣẹ fún un, ọ̀kẹ́ àìmọye sì ni àwọn tí wọ́n dúró níwájú rẹ̀. Ìdájọ́ bẹ̀rẹ̀, a sì ṣí àwọn ìwé sílẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Iṣàn iná nṣẹyọ, o si ntu jade lati iwaju rẹ̀ wá; awọn ẹgbẹ̃gbẹrun nṣe iranṣẹ fun u, ati awọn ẹgbẹgbarun nigba ẹgbarun duro niwaju rẹ̀: awọn onidajọ joko, a si ṣi iwe wọnni silẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Odò iná ń ṣàn ó ń jáde ní iwájú u rẹ̀ Àwọn ẹgbẹ̀rún lọ́ná ẹgbẹ̀rún ń forí balẹ̀ fún un; Ọ̀nà ẹgbẹ̀rún mẹ́wàá lọ́nà ẹgbẹ̀rún mẹ́wàá sì dúró níwájú u rẹ̀. Àwọn onídàájọ́ jókòó a sì sí àwọn ìwé sílẹ̀.