Daniel 7:15 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
“Ìran tí mo rí yìí bà mí lẹ́rù pupọ, ọkàn mi sì dààmú.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ẹmi emi Danieli si rẹwẹsi ninu ara mi, iran ori mi si mu mi dãmu.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Ọkàn èmi Dáníẹ́lì, dàrú, ìran tí ó wá sọ́kàn mi dẹ́rù bà mí.