Daniel 7:3 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àwọn ẹranko ńláńlá mẹrin bá jáde láti inú òkun. Ọ̀kan kò jọ̀kan ni àwọn mẹrẹẹrin.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ẹranko mẹrin nla si ti inu okun jade soke, nwọn si yatọ si ara wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ẹranko ńlá mẹ́rin tí ó yàtọ̀ sí ara wọn, jáde láti inú òkun náà.