Deuteronomy 1:32 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Sibẹsibẹ ẹ kò gba OLUWA Ọlọrun yín gbọ́,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Sibẹ̀ ninu nkan yi ẹnyin kò gbà OLUWA Ọlọrun nyin gbọ́.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Pẹ̀lú gbogbo èyí tí mo wí, ẹ kò gbẹ́kẹ̀lé OLÚWA Ọlọ́run yín,