Deuteronomy 14:11 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
“Ẹ lè jẹ gbogbo àwọn ẹyẹ tí wọ́n bá mọ́.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Gbogbo ẹiyẹ ti o mọ́ ni ki ẹnyin ki o ma jẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ẹ lè jẹ ẹyẹ tí ó bá mọ́.