Deuteronomy 18:17 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
OLUWA wí fún mi nígbà náà pé, ‘Gbogbo ohun tí wọ́n sọ patapata ni ó dára.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
OLUWA si wi fun mi pe, Nwọn wi rere li eyiti nwọn sọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
OLÚWA sì wí fún mi pé, “Ohun tí wọ́n sọ dára.