Deuteronomy 18:20 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ṣugbọn wolii tí ó bá fi orúkọ mi jẹ́ iṣẹ́ tí n kò rán an, tabi tí ó jẹ́ iṣẹ́ kan fun yín ní orúkọ àwọn oriṣa, wolii náà gbọdọ̀ kú ni.’
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn wolĩ na, ti o kùgbu sọ ọ̀rọ kan li orukọ mi, ti emi kò fi fun u li aṣẹ lati sọ, tabi ti o sọ̀rọ li orukọ ọlọrun miran, ani wolĩ na yio kú.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n bí wòlíì kan bá kùgbù sọ ọ̀rọ̀ kan tí èmi kò paláṣẹ fún un láti sọ ni orúkọ ọ mi tàbí wòlíì tí ó sọ̀rọ̀ ní orúkọ ọlọ́run mìíràn, irú wòlíì bẹ́ẹ̀ ní láti kú.”