Deuteronomy 2:15 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
OLUWA dójúlé wọn nítòótọ́ títí gbogbo wọn fi parun patapata ninu ibùdó àwọn ọmọ Israẹli.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Pẹlupẹlu ọwọ́ OLUWA lodi si wọn nitõtọ, lati run wọn kuro ninu ibudó, titi nwọn fi run tán.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ọwọ́ OLÚWA sì wà lára wọn fún ibi títí gbogbo wọn fi run tan nínú ibùdó.