Deuteronomy 2:23 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àwọn ará Afimu ni wọ́n ti ń gbé àwọn ìletò tí wọ́n wà títí dé Gasa tẹ́lẹ̀ rí, ṣugbọn àwọn kan tí wọ́n wá láti Kafitori ni wọ́n pa wọ́n run, tí wọ́n sì tẹ̀dó sí ilẹ̀ wọn.)
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati awọn ọmọ Affimu ti ngbé awọn ileto, titi dé Gasa, awọn ọmọ Kaftori, ti o ti ọdọ Kaftori wá, run wọn, nwọn si ngbé ibẹ̀ ni ipò wọn.)
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nípa ti àwọn ará Áfì, tí wọ́n ń gbé ní àwọn ìlú kéékèèkéé dé Gásà, àwọn ará Káfórì, tí wọ́n jáde láti Kírétè wá ni ó pa wọ́n run, wọ́n sì gba ilẹ̀ wọn.)