Deuteronomy 2:26 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
“Nítorí náà mo rán àwọn oníṣẹ́ láti aṣálẹ̀ Kedemotu, sí Sihoni, ọba Heṣiboni. Iṣẹ́ alaafia ni mo rán sí i, mo ní,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Mo si rán onṣẹ lati aginjù Kedemotu lọ sọdọ Sihoni ọba Heṣboni pẹlu ọ̀rọ alafia, wipe,
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Mo rán àwọn ìránṣẹ́ sí Síhónì láti ihà Kédémótì pẹ̀lú ọ̀rọ̀ àlàáfíà wí pé,