Deuteronomy 20:15 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Bẹ́ẹ̀ ni ẹ óo ṣe sí àwọn ìlú tí ó jìnnà sí yín, tí kì í ṣe àwọn ìlú orílẹ̀-èdè tí ó wà níhìn-ín.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Bayi ni ki iwọ ki o ṣe si gbogbo ilu ti o jìna rére si ọ, ti ki iṣe ninu ilu awọn orilẹ-ède wọnyi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Báyìí ni ìwọ yóò ṣe sí gbogbo ìlú tí wọ́n wà ní ọ̀nà jínjìn sí ọ tí wọn kò sì tara àwọn orílẹ̀ èdè tí ó wà lẹ́gbẹ̀ẹ́ ẹ̀ rẹ.