Deuteronomy 20:17 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Rírun ni kí ẹ run gbogbo wọn patapata, gbogbo àwọn ará Hiti, ati àwọn ará Amori, ati àwọn ará Kenaani, ati àwọn ará Perisi, ati àwọn ará Hifi, ati àwọn ará Jebusi; gẹ́gẹ́ bí OLUWA Ọlọrun yín ti pa á láṣẹ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn ki iwọ ki o pa wọn run patapata; awọn ọmọ Hitti, ati awọn Amori, awọn ara Kenaani, ati awọn Perissi, awọn Hifi, ati awọn Jebusi; bi OLUWA Ọlọrun rẹ ti paṣẹ fun ọ:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Pa wọ́n run pátapáta, àwọn ọmọ Hítì, ọmọ Ámórì, ọmọ Kénánì, ọmọ Pérísì, ọmọ Hífì, ọmọ Jébúsì gẹ́gẹ́ bí OLÚWA Ọlọ́run rẹ ti pa á láṣẹ fún ọ.