Deuteronomy 22:18 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àwọn àgbààgbà ìlú náà yóo mú ọkunrin yìí, wọn yóo nà án dáradára.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ki awọn àgba ilu na ki o si mú ọkunrin na ki nwọn ki o si nà a;
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
àwọn àgbààgbà yóò sì mú ọkùnrin náà, wọn yóò sì jẹ́ ẹ́ níyà.
Recommended Reading